Ẹnyin Ènìa mi, kére, o! Ẹ sì ku dédé ìwòyí, o.
Ẹ jọ̀wọ́ ẹ ba’mi gba ọ̀rọ̀ awọn ènìa mi ni ilu Ọ̀ṣún ti BBC mā gbé kalẹ̀ ni ọjọ́ Ẹtì ti nṣe ọjọ́ kẹrìnlá oṣù k’ẹsán (Friday, September 14, 2018) ni agogo mẹsán òwúrọ̀ (9.00 a.m.) ni àkokò ti awọn òṣèlú fuń ipò Gómìnà yi o fi ọ̀rọ̀ j’omi toro ọ̀rọ̀ fun eré ìdíje na.
Ẹ jọ̀wọ́ ẹ ba’mi fi ẹ̀dà (copy) ìkedé yi ṣ’ọwọ́ si awọn ènìa wa ni ẹ̀yìn òkún, ni pàtàkì ni ìlú Ọba (the UK) as the BBC is still trying out a run, and if the audience justifies it, BBC Yoruba would become a regular feature.
Let’s all give the BBC our support through this unique medium, [a sort of] k’a fi òkò kan pa ẹiyẹ mejì!
Oduà a gbé gbogbo wa, o. Èmi ni ti nyín nitòótọ,
TOLA ADENLE.
https://www.bbc.com/yoruba/44905220
==================================================================================
From: Adebayo OPAWOYE
Date: Mon, Sep 10, 2018 at 2:58 PM
Subject: Fwd: Idibo Ọsun: BBC Yoruba yóò se ìfọ̀rọ̀wérọ̀ pẹ̀lú àwọn olúdíje – BBC News Yorùbá
===================================================================================
MONDAY, SEPTEMBER 10, 2018. 5:28 P.M. [GMT]
September 10, 2018
General, Yoruba: Essays & Academic Workshops, papers etcetera